S/N int64 1 436 | statement stringlengths 18 253 | A1 stringclasses 2
values | A2 stringclasses 2
values | A3 stringclasses 2
values | target stringclasses 2
values | source stringclasses 6
values | text_origin stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|---|---|
401 | Ẹni tó kékọ̀ọ́ gboyè fásitì sàn ju bàbá olówó tí kò kàwé lọ | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
402 | Mo fi àkókò yí rọ gbogbo àwọn alátìlẹ́yìn Manchester United láti jẹ oúnjẹ alẹ́ wọn kí wọ́n tó lọ wo eré bọ́ọ̀lù náà. Nítorí iṣu Manchester United ma sùn sínú epo Liverpool lónìí | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
403 | Ẹ̀dá ò láròpin! Anfààní Àdúgbò FC, ìyẹn Manchester United, táyé ti sọ irètí nù lórí wọn lu Liverpool lálùmólè bí àpò ẹ̀wà | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
404 | Arsenal Erin lákátabú Oriogbade FC ti gòkè àlọ̀, Fulham ni wọ́n fi șe ìrúbọ àti gorí tábìlì EPL | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
405 | Lórí erinlákátabú Arsenal tó ń pa kúkúrú, tó ń pa gúngùn ninu EPL yìí, Bàbá gba ọpẹ́ wa | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
406 | Lẹ́yìn ìṣẹ́jú mókànlélógún ifesewonse pẹ̀lú Chelsea, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nottingham Forest fi ọwọ́ òsì júwe ilé fún Ange Postecoglou bíi akọ́nimọ̀ọ́gbá | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
407 | Àwọn ọmọ ìyá aláró, ìyẹn Chelsea, fẹ́ràn káàdì pùpá púpọ̀ 😂😂 | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Facebook | original |
408 | Ẹ̀jẹ̀ lẹ́nu ọ̀daràn, Aníyìkáyé, ìyẹn Chelsea, fún Nottingham Forest lọ́rùn pa bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n Șépè káàdì pupa fún wọn | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
409 | Hmmm, Oshimen fakọyọ ṣùgbọ́n ẹni tí a lè mú ní à ń lẹ̀dí mọ́ ló bá dé ní pápá ìṣeré Uyo lálẹ́ yìí pẹ̀lú Benin Republic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
410 | Super Eagles fi Benin Republic șe àsun pẹ̀lú ìrètí láti lọ fún ìdíje Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
411 | Ìyàwó dùn lọ́sìngín! Gómìnà Abba Kabir Yusuf ti ìpínlẹ̀ Kano, ní ìjọba òun yóò ṣẹ́gun àgbèrè ṣíṣe látàrí àì lọ́kọ-láya | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
412 | Ìjọba Kano fẹ́ẹ́ șe igbéyàwó fún èèyàn ẹgbẹ̀rún méji láti ran àwọn tí kò r'ówó șe é lówó, dẹ́kun ṣìná ṣíṣe | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
413 | Àyànmó Super Eagles Nàìjíríà tún yí bírí bírí ní ìrìnàjò àti pegedé fún ìdíje Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n yan Lesotho jẹ | non-sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | BBC News | original |
414 | Àsikò tí wọ́n máa ń sọ pé oríléèdè Naijiria ni ìwà ìbàjẹ́ tó pò jùlọ lágbàáyé ti kọjá | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
415 | Aníyikáyé FC ìyẹn Chelsea bínú tán, òròmọ adìyẹ wọn fi àṣá Liverpool ṣe Súyà jẹ | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
416 | Ànfààní Àdúgbò iyen Manchester United, tọ́ àṣeyorí wò, wọ́n kanra lu Sunderland lónìí | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
417 | Oriogbade Arsenal yarí kanlẹ̀, àlùmọ́lẹ̀ bí ìlú bẹ̀ǹbẹ́ ni wọ́n lu West Ham ní Emirates | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
418 | Kò sí bí o bá ṣe ń jìyà tó, má ṣe béèrè ìrànlọ́wọ́ lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé o lè kú nígbà sórí ìjìyà náà, kò sí ẹni tí yóò lè sọ pé òun ti ràn ọ́ lọ́wọ́ rí | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
419 | Tí o bá mọ̀ pé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ máa ń ṣe òògùn owó, má ṣe sá fún. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lè padà lò ọ́ fún òògùn owó, tí o sì máa kú, tìrẹ ni yóò jẹ́ ìkẹyìn. | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | BBC News | original |
420 | Bàba kúdí ga ní ènìyàn, ó kàn nílátí gun àga kí ẹ tó ó ri ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
421 | O ti yó lo wí, o sì ṣíwọ́ nídì Àmàlà | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
422 | O kò lẹ́jọ́ láti rò, ẹnu rẹ kò sì dúró | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
423 | Mo láṣọ, mo láṣọ, abájọ tí wọ́n fi ṣi ọ̀ kó mọ́ wèrè | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
424 | Ó jẹun ó yó lótìtọ́, bíbẹ́kọ̀ yóò ti ṣe gbé abọ́ agbe | sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
425 | Ara mi kò gba èpè ni kò jẹ ki n ṣílẹ̀kùn fún ọ̀tá | non-sarcastic | sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | Crowdsourcing | original |
426 | Mò n bọ̀, n ò tí ì dé | non-sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | Crowdsourcing | original |
427 | Tó bá dé odò ẹni tí mo rán ẹ lọ ṣe àbẹ̀wò rẹ̀, ní ṣe ni ko sùn síbẹ̀, sé o gbọ́? | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
428 | Títí mọ̀wé ju kí ó ṣe ipò kíní lọ | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Crowdsourcing | original |
429 | Ẹni tí a ní kí ó se nǹkan, tí o jẹ wípé òdì ló ń ṣe | non-sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | non-sarcastic | Crowdsourcing | original |
430 | Nígbà tí o padà lówó lọ́wọ́ nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín ní ìgbésí ayé rẹ, má ṣe gbàgbé àwọn tí wọ́n ń ràn ọ́ lọ́wọ́ kí owó tó dé, kí o tèbè sọ òǹkà ìpè wọn dànù kí wọ́n tó rántí rẹ, bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ọlọ́run lè fìyà jẹ ọ́ nítorí náà. | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
431 | Tí o bá ti bí ọmọ kan tí o kò sì ní owó láti kọ́ ọ, bí ọmọ méjì sí i. Àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yóò máa ṣe wàhálà papọ̀ nígbà tó bá yá, bó tilẹ̀ jẹ́ pé o lè má jàǹfààní èyíkéyìí nínú wọn. | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
432 | Tí o bá ń ṣe ìwà ẹ̀tàn tí agbófinró Nàìjíríà kan bá gbá ọ mú, jẹ́ kí wọ́n ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ rẹ kí o sì sọ ohun tí o ń ṣe fún wọn, bó tilẹ̀ jẹ́ wípé o lè padà ṣẹ̀wọ̀n | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
433 | Tí o bá jẹ́ ọkùnrin tí o sì ń rí owó, fi owó dá ọ̀rẹ́bìnrin rẹ lóko òwò kí o tó tọ́jú àwọn òbí rẹ, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lè fi ọ́ sílẹ̀ nígbà tí o kò bá lówó lọ́wọ́ mọ́, àmọ́ o ti ṣe ìgbìyànjú. | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
434 | Tí o bá fẹ́ gbéyàwó tí o sì ní láti yan láàrín ẹni tí ó ní ìdí ńlá àti ẹni tí ó ní ìwà rere, o yẹ kí o yan èyí àkọ́kọ́ fún láti lè máa fi yangàn, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lè máa dààmú ìgbésí ayé rẹ àti ti ìdílé rẹ nígbà tó bá yá. | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
435 | Tí olè bá ń jalè níbì kan tí àwọn ènìyàn sì ń sá lọ, má ṣe sá lọ, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, wọ́n á rí ọ gẹ́gẹ́ bí ojo, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n lè pa ọ́. | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
436 | Nítorí pé o kò ní owó kò túmọ̀ sí pé o kò gbọ́dọ̀ fẹ́ ìyàwó méjì, nítorí pé ìyàwó kejì lè mú oríire wá fún ìdílé rẹ, bó tilẹ̀ jẹ́ pé gbogbo yín lè kú sínú ìyà | sarcastic | sarcastic | sarcastic | sarcastic | Instagram | original |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.